Hymn 917 – A dupe Oluwa | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "A dupe Oluwa" (C&S Hymn #917, Yoruba). 1. A dupe Oluwa F‘ajodun oni O da emi wa si Ogo f’oko Re Pelu orin ayo L'a o fi…

Hymn 917 – A dupe Oluwa | C&S Yoruba Hymnary
1. A dupe Oluwa F‘ajodun oni O da emi wa si Ogo f’oko Re Pelu orin ayo L'a o fi josin Fun bukun aye wa On reti orun. Egbe: Ajodun de, e yo Ke, AIeluya A m 'ore ope wa Tewo gb’ore wa. 2. Opo l'elegbe wa Ni ko tun si mo Opo ti sako lo Kuro lodo Krist A dupe Oluwa Pe O da wa si O si tun ka wa ye F’ajodun oni. Egbe: Ajodun de, e yo... 3. Baba wa li orun Awa se pinu Pe ao sin Jesu L'ojo aye wa A o sise fun dagba Soke ijo wa Tit‘ ao fi je ‘pe Re Fun ‘simi orun. Egbe: Ajodun de, e yo... 4. Wo Oluw'ajodun A f’ope fun O Je k’ire ajodun kari gbogbo wa A be O, Olorun Fun wa l’agbara Lati sin O d'opin Ojo aye wa. Egbe: Ajodun de, e yo Ke, AIeluya A m 'ore ope wa Tewo gb’ore wa. Amin

Hymn 917 – A dupe Oluwa | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia