Hymn 916 – O ha ngbekele Jesu n’gbogbo‘ona re | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "O ha ngbekele Jesu n’gbogbo‘ona re" (C&S Hymn #916, Yoruba). 1. O ha ngbekele Jesu n’gbogbo‘ona re O ha nd'otun lokan…

Hymn 916 – O ha ngbekele Jesu n’gbogbo‘ona re | C&S Yoruba Hymnary
1. O ha ngbekele Jesu n’gbogbo‘ona re O ha nd'otun lokan re lojojumo O ha joni eyin Re? ye oro Re wo Y’o fun o l'Emi Mimo lopolopo. Egbe: Lopolopo si, lopolopo si Ki won Ie ni iye si lopolopo si Lopolopo si, Iopolopo si Ki won le ni iye si Iopolopo. 2. Fun oju rere Re, gbe oko Re ga Olugbala wa to t’orun sokale K'awon ayanfe Re juba oro Re Eni ra wa pada nipa eje Re. Egbe: Lopolopo si, lopolopo si... 3. Wa pelu igbagbo, wa je ipe Re Eyin t’a mbukun, jowo ara yin fun Jesu, y‘o gb'eni t'o sda wa sodo Re T'o da ‘bukun Re lu o lopolopo. Egbe: Lopolopo si, lopolopo si Ki won Ie ni iye si lopolopo si Lopolopo si, Iopolopo si Ki won le ni iye si Iopolopo. Amin

Hymn 916 – O ha ngbekele Jesu n’gbogbo‘ona re | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia