Hymn 906 – ORE wo l’a ni bi Jesu | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "ORE wo l’a ni bi Jesu" (C&S Hymn #906, Yoruba). 1. ORE wo l’a ni bi Jesu Ti O ru ‘banuje wa Anfaani wo I’o po bayi…

Hymn 906 – ORE wo l’a ni bi Jesu | C&S Yoruba Hymnary
1. ORE wo l’a ni bi Jesu Ti O ru ‘banuje wa Anfaani wo I’o po bayi Lati maa gbadura si I Alaafia pupo l’a n sonu Iror’ainidi l’a n je ‘Tori a ko n fi gbogbo nnkan S’adura niwaju Re. 2. Idanwo ha wa fun wa bi? A ha ni wahala bi A ko gbodo so ‘reti nu Sa gbadura s‘Oluwa, A'a le ri ore olooto Ti o Ie ba wa daro Jesu ti mo ailera wa, Sa gbadura s'Oluwa. 3. Eru han won wa l'orun bi? Aniyan ha po fun wa? Olugbala ni aabo wa, Sa gbadura s‘Oluwa Awon ore ha sa o ti? Sa gbadura s’Oluwa Yoo gbe o soke l’apa Re, lwo yoo si n'itunu. Amin

Hymn 906 – ORE wo l’a ni bi Jesu | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia