Hymn xli – Awa wole Baba | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "Awa wole Baba" (C&S Hymn #xli, Yoruba). Awa wolẹ Baba, ) Ijọ Séráfù de loni o ) 2ce Ọba onibu ọrẹ, Tiwa lẹyin lati…
Awa wolẹ Baba, ) Ijọ Séráfù de loni o ) 2ce Ọba onibu ọrẹ, Tiwa lẹyin lati Sioni wa, Eledumare ran wa lọwọ, Gb'ẹbọ sisun wa loni o, Mu gbogbo ibere wa sẹ, ‘Gba yi la to mọ pe Oluwa ti gba wa la o, Gbọ lati 'bugbe Rẹ — Eledumare, Ibukun owo fi fun wa, Ibukun ọmọ fi fun wa, Alafia fi fun wa. Abiyamọ kii gbọ igbe ọmọ Rẹ, Ko ma ta kiji, Eledumare Baba rere wa fi, fun wa. Awa wolẹ Baba, Ẹgbẹ Séráfù de loni o, Ọba onibu ọrẹ. Abiyamọ kii gbọ igbe ọmọ Rẹ, Ko ma ta kiji, Eledumare Baba rere wa fi, fun wa. ASẸ Abiyamọ kii gbọ igbe ọmọ Rẹ, Ko ma ta kiji, Eledumare Baba rere wa fi, fun wa.
Hymn xli – Awa wole Baba | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia