Hymn xlii – Baba Mimo jowo a de o | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "Baba Mimo jowo a de o" (C&S Hymn #xlii, Yoruba). Baba Mimọ jọwọ a de o, ) Ninu Ijọ Rẹ - Baba, ) 2ce Olugbala sunmọ wa…
Baba Mimọ jọwọ a de o, ) Ninu Ijọ Rẹ - Baba, ) 2ce Olugbala sunmọ wa — Ẹlẹru niyin o, ) Olugbala sunmọ wa — Ẹlẹru niyin o, Olugbala sunmọ wa — Ẹlẹru niyin o. Fun wa lowo si fun wa lọmọ o, Ninu Ijọ Rẹ o Baba, Olugbala gbohun wa Ẹlẹru niyin o. Fun wa lọgbọn si fun wa loye o, Ninu Ijọ Rẹ o - Baba, Olugbala gbohun wa — Ẹlẹru niyin o, Olugbala gbohun wa — Ẹlẹru niyin o, Olugbala gbohun wa — Ẹlẹru niyin o. ASẸ
Hymn xlii – Baba Mimo jowo a de o | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia