Hymn 899 – Baba dariji wa o | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "Baba dariji wa o" (C&S Hymn #899, Yoruba). Baba dariji wa o, ) 2ce Awa ẹlẹsẹ abara m'ore jẹ, Baba dariji wa o, Ni ti…
Baba dariji wa o, ) 2ce Awa ẹlẹsẹ abara m'ore jẹ, Baba dariji wa o, Ni ti mimọ a ko mọ, ) Ni ti yiyege a ko ye'ge )2ce Bi a ba ni ka s'ami ẹsẹ, Ko s'ẹni to le duro ninu wa— Baba Ọrun - Jọwọ dariji wa o. Ya wa si mimọ ) 2ce Jẹ ka le wulo fun isẹ Rẹ, Ya wa si mimọ, Ogun aye — Ogun Esu, ) 2ce Ma jẹ ko de wa lọna, Ninu ara — Ninu ẹmi, Ma jẹ k'adura wa ni 'de na, Ya wa si mimọ. ASẸ
Hymn 899 – Baba dariji wa o | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia