Hymn xxxiii – Dari ese ji wa | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "Dari ese ji wa" (C&S Hymn #xxxiii, Yoruba). Dari ẹsẹ ji wa, ) Ọlọrun o — Ọlọrun wa ) Dari ẹsẹ ji wa, ) 2ce Atobiju…
Dari ẹsẹ ji wa, ) Ọlọrun o — Ọlọrun wa ) Dari ẹsẹ ji wa, ) 2ce Atobiju Ọlọrun wa, ) Awa mọra wa ni ẹlẹsẹ, Abara more jẹ, Bi akisa ẹlẹgbin o, L'ẹsẹ ni waju Rẹ, Ni kutukutu a bẹ Ọ o Ẹlẹruniyin, Loni o awa wolẹ — saanu fun wa. Baba-Baba, Jọwọ wa gbadura wa — Baba (a) K'aye wa kó loyin, ) ) (b) K'ọrọ wa ko d'ayọ ) (c) Ki'le wa ko roju, ) Baba - Baba, ) (d) K'ọna wa ko l'ayọ, ) gbadura wa, ) Baba. (e) K'aboyun bi were ) ) (f) K'agan t'ọwọ bosun, ) Ni kutukutu a bẹ Ọ o — Ẹlẹru niyin, Loni o awa wolẹ —saanu fun wa. ASẸ (c) Ki'le wa ko roju, ) Baba - Baba, ) (d) K'ọna wa ko l'ayọ, ) gbadura wa, ) Baba. (e) K'aboyun bi were ) ) (f) K'agan t'ọwọ bosun, )
Hymn xxxiii – Dari ese ji wa | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia