Hymn xxxii – Gbogbo wa t'ewo adura | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "Gbogbo wa t'ewo adura" (C&S Hymn #xxxii, Yoruba). Gbogbo wa t'ẹwọ adura, Ọlọrun o saanu fun wa, L'ọmọde l'agba awa…

Hymn xxxii – Gbogbo wa t'ewo adura | C&S Yoruba Hymnary
Gbogbo wa t'ẹwọ adura, Ọlọrun o saanu fun wa, L'ọmọde l'agba awa wolẹ Messiah Baba wa, Bi a ba wi pe awa ko d'ẹsẹ ) A n tan 'ra wa jẹ, ) 2ce Otitọ kan ko si ninu wa o — Ọlọrun wa, Nitori Jesu — dariji wa Baba. Isin wa oni d'ọwọ Rẹ — Olu Messiah, ) Ẹbẹ wa oni d'ọwọ Rẹ — Olu Messiah, )2ce Jẹ ko jẹ itẹwọgba — Ọlọrun Mose. Gbogbo wa t'ẹwọ adura, Ọlọrun o saanu fun wa, L'ọmọde l'agba a wa wolẹ Messiah Baba wa. ASẸ

Hymn xxxii – Gbogbo wa t'ewo adura | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia