Hymn xxxv – Loni awa de o lati juba Re | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "Loni awa de o lati juba Re" (C&S Hymn #xxxv, Yoruba). Loni awa de o lati juba Rẹ, ) Iwọ nikan lawa yoo ma sin, ) 2ce…
Loni awa de o lati juba Rẹ, ) Iwọ nikan lawa yoo ma sin, ) 2ce Buruburu lawa ba, Lati gb'ohun wa soke si Ọ, ) 2ce Messiah, Ogo ni fun Ọ o — iyin fun Ọ, loni Eledua ye sọkalẹ - Wa ba wa pe, Jẹ ki oni yẹ wa o, Ọlọjọ oni a' mbẹ Ọ, Amin Amin ko sẹ Baba un un, K'aye wa dun ko l'oyin, Ọlọjọ oni a mbẹ Ọ, Amin ko sẹ Baba un un, K'aboyun bi tibi tire, K'awọn agan d'ọlọmọ, Amin — Amin ko sẹ Baba un un, Awọn ti n wa'sẹ ko risẹ se, K'Ọlọmọ ma p'adanu Amin — Amin ko sẹ Baba un un, Buruburu la wa ba, Lati gb'ohun wa soke si Ọ, ) 2ce Messiah, Ogo ni fun Ọ o — lyin fun Ọ loni, Eledua ye sọkalẹ — Wa ba wa pe.
Hymn xxxv – Loni awa de o lati juba Re | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia