Hymn 894 – ODUN miiran tun ti de | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "ODUN miiran tun ti de" (C&S Hymn #894, Yoruba). 1. ODUN miiran tun ti de Ona t’a ko rin ri Yoo fun mi ni ikilo…

Hymn 894 – ODUN miiran tun ti de | C&S Yoruba Hymnary
1. ODUN miiran tun ti de Ona t’a ko rin ri Yoo fun mi ni ikilo B’iranlowo ko si Sugbon Eni t’O to mi Ni odun t’o koja Se ‘leri p’Oun yoo duro Ti mi nigba gbogbo. 2. Odun mii pelu Jesu Emi ko mo ‘foya Yebiye ni ife Re B'o ti wu k’iji le Gba t'iji ba tile le No sinmi ninu Re No r’alaafia didun Ni ookan aya Re. 3. Odun ti n o gbekele E N o tun gbekele I'Eni Ti koja mi kule ri Gba ti mo n wo’oju Re O f’ogo at'opa Re Fun mi, fun okun mi Jeejee l’O si n to mi lo L‘ona mi lo s'ile. 4, Odun miiran lnti sin in Ki n s‘ise fun un nihin Gba l’ojiji tile gun Orun tun n sunmo le N ko mo gba ti yoo pe mi Lati f'ise sile je ki n le je olooto B’ojo ti n sure lo. 5. Odun miiran lati fe E Eni ti mo feran Odun miiran lati yin in Pelu orin segun Ohun t’ola le mu wa Banuje tab'iya lfe Re duro laelae Okan naa ni titi. 6. Odun mii pelu Jesu Oluwa mo dupe F‘oju Re ti ki i kuna L’ona ajo aye Joo maa to mi, Oluwa Ko mi ki n se ‘fe Re Si mu ete ti Re se L‘aye mi l’ojoojo. Amin

Hymn 894 – ODUN miiran tun ti de | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia