Hymn 895 – LORI oke lehin 'lu l‘agbelebu | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "LORI oke lehin 'lu l‘agbelebu" (C&S Hymn #895, Yoruba). 1. LORI oke lehin 'lu l‘agbelebu kan wa Apere iya at‘egan Okan…

Hymn 895 – LORI oke lehin 'lu l‘agbelebu | C&S Yoruba Hymnary
1. LORI oke lehin 'lu l‘agbelebu kan wa Apere iya at‘egan Okan mi fa sibe, s’Olufe mi owon T‘a pa f’ese gbogbo aye. Egbe: Emi yoo gbe agbelelu re Titi n fo fi pari ajo mi Emi o ro m agbelebu naa K’emi le de ade n'ikehin. 2. Agbelebu naa t’awon araye kegan Oun l'o ni ewa l‘oju mi, ‘Tori Om’Olorun, bo ogo Re sile O si ti ru u lo si Kalfari. Egbe: Emi yoo gbe agbelelu re... 3. L'ar'agbelebu naa, t'eje mimo san si Mo r‘ewa iyanu nibe Tori pe lori re, Jesu jiya o ku O dariji, o we mi mo. Egbe: Emi yoo gbe agbelelu re... 4. Emi yoo j’olooto s’Emiti t’O ku fun mi Ngo f’ayo r’egan oun tiju Nigboose yoo pe mi lo le ayeraye Ki n le n‘ipin ninu ogo Re. Egbe: Emi yoo gbe agbelelu re Titi n fo fi pari ajo mi Emi o ro m agbelebu naa K’emi le de ade n'ikehin. Amin

Hymn 895 – LORI oke lehin 'lu l‘agbelebu | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia