Hymn 889 – OKAN wa kun f'ayo loni | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "OKAN wa kun f'ayo loni" (C&S Hymn #889, Yoruba). 1. OKAN wa kun f'ayo loni A ti r‘ona wura na Imole re nta l‘ona wa A…
1. OKAN wa kun f'ayo loni A ti r‘ona wura na Imole re nta l‘ona wa A ti r’ona wura na O ti pe t’ayun Re nyun wa Larin ayidayid’ aye Die lo ku fun wa k'o bo K'a to r‘ona wura na. Egbe: Nje korin, korin ayo F'okan ayo korin soke Imole de, a de ‘ile wa Ati r'ona wura na. 2. A pe wa kuro l'aye yi A ti r‘ona wura na Ore wa gbogbo wa nibe A ti r'ona wura na Awa jeri pe didun na K'a ma tase ijoba orun Pelu Jesu a nlo ‘le wa A ti r‘ona wura na. Egbe: Nje korin, korin ayo... 3. Kiun ni ‘danwo wa t‘o koja A ti t'ona wura na Ayo ile mu k’a gbagbe A ti r’ona wura na ‘Ji kuku ko ni pe kuro lfayabale yoo si de A ta ‘gbokun, oko si gun le A ti r’ona wura na. Egbe: Nje korin, korin ayo... 4. Pel'okan ‘es‘Olorun wa A ti r’ona wura na Lekan ri ti a ti sonu A ti r‘ona wura na A fe d’odo Olugbala Jesu yoo f'ayo gba wa O je nipa or’ofe nikan A ti r‘ona wura na. Egbe: Nje korin, korin ayo... 5. A dupe low’Olorun wa Ti p’a r’ona wura na Iyin, ogo ope, ola Fun Baba ati Omo Ati pelu Emi Mimo Metalokan ayeraye Titi aye lao ma yin Pe a r'ona wura na. Egbe: Ope ni fun O Elshadai Jehofa Rofai ni k’ayin Aleluya orin iyin Fun Metalokan soso. Amin
Hymn 889 – OKAN wa kun f'ayo loni | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia