Hymn xxiv – Awa tun de — awa tun de | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "Awa tun de — awa tun de" (C&S Hymn #xxiv, Yoruba). Awa tun de — awa tun de, Awa juba Baba, Awa wolẹ l'eekun wa —…

Hymn xxiv – Awa tun de — awa tun de | C&S Yoruba Hymnary
Awa tun de — awa tun de, Awa juba Baba, Awa wolẹ l'eekun wa — Olodumare, Sọkalẹ wa — Wa ba wa pe, Jẹ ki isin wa oni — le jẹ tẹwọgba. Ọpẹ Ibukun fi fun wa ) K'ile roju fun wa, ) Je ki isin K'ara dẹ gbogbo wa, ) wa oni le K'ọlọmọ ma padanu, ) jẹ tẹwọgba. K'agan ko d'ọlọmọ ) Awa tun de — awa tun de Awa wolẹ Baba, Awa wolẹ l'ekun wa Olodumare, Jẹ ki isin wa oni le jẹ tẹwọgba. ASẸ

Hymn xxiv – Awa tun de — awa tun de | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia