Hymn 890 – Awa ni Baba ni igbejo | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "Awa ni Baba ni igbejo" (C&S Hymn #890, Yoruba). Awa ni Baba ni igbẹjọ, Ẹjọ wa are ni, Nitori Jesu nikan, Dariji wa…
Awa ni Baba ni igbẹjọ, Ẹjọ wa are ni, Nitori Jesu nikan, Dariji wa Baba, Nitori Jesu nikan, Dariji wa o. Ẹsẹ irọ — Ẹsẹ ole............. Dariji wa Baba, Ẹsẹ ebu ati isọkusọ........... Dariji wa o, Ẹsẹ iganni ati isata............ Dariji wa Baba, Dakun o — Olu Ọrun......... Dariji wa o. Awa ni Baba ni igbẹjọ, Ẹjọ wa are ni, Nitori Jesu nikan — Dariji wa-Baba, Nitori Jesu nikan — Dariji wa o. ASẸ
Hymn 890 – Awa ni Baba ni igbejo | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia