Hymn xxiii – Awa elese de o — awa juba Baba | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "Awa elese de o — awa juba Baba" (C&S Hymn #xxiii, Yoruba). Awa ẹlẹsẹ de o — awa juba Baba ) 2ce Bẹlẹjọ ba m'ẹjọ rẹ…

Hymn xxiii – Awa elese de o — awa juba Baba | C&S Yoruba Hymnary
Awa ẹlẹsẹ de o — awa juba Baba ) 2ce Bẹlẹjọ ba m'ẹjọ rẹ l'ẹbi, Ko ni pẹ ni kunlẹ, Awa jẹwọ ẹsẹ wa Baba — da wa lare, Awa sa ti sẹ o, Baba dakun ka wa yẹ loni i . K'iku mase pa wa, ) Kárùn ma gbe wa de ) Baba dákun ka Pese fun aini wa, ) wa ye loni. Awa jẹwọ ẹsẹ wa - Baba da wa lare, Awa sa ti sẹ o, Baba dakun ka wa yẹ loni. ASẸ

Hymn xxiii – Awa elese de o — awa juba Baba | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia