Hymn xxii – Wa gbo tiwa — Wa gbo tiwa | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "Wa gbo tiwa — Wa gbo tiwa" (C&S Hymn #xxii, Yoruba). Wa gbọ tiwa — Wa gbọ tiwa ) Ẹmi Mimọ o - Wa gbọ ti wa )2ce Iwọ la…

Hymn xxii – Wa gbo tiwa — Wa gbo tiwa | C&S Yoruba Hymnary
Wa gbọ tiwa — Wa gbọ tiwa ) Ẹmi Mimọ o - Wa gbọ ti wa )2ce Iwọ la wa gb'oju le, Iwọ la wa f'ọkan tẹ, Ẹgbẹ Séráfù wa ke pe Ọ o, Wa gbọ ti wa, Wa gbọ ti wa - Wa gbọ ti wa, Ẹmi Mimọ o - Wa gbọ ti wa, Ki a ma pofo — Ki a ma r'ofo o, Ki a ma gunlẹ, ofo laye Wa gbọ tiwa - Wa gbọ tiwa, Ẹmi Mimọ o - Wa gbọ ti wa. ASẸ

Hymn xxii – Wa gbo tiwa — Wa gbo tiwa | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia