Hymn xxi – Olu Ọrun awa de | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "Olu Ọrun awa de" (C&S Hymn #xxi, Yoruba). Olu Ọrun awa de ) Ba ti juba fun Ọ o, )2ce Ẹmi Ọrun jọwọ — Wa gbọ ti wa, )…
Olu Ọrun awa de ) Ba ti juba fun Ọ o, )2ce Ẹmi Ọrun jọwọ — Wa gbọ ti wa, ) Kini ka fi tuba ẹsẹ, wa — ara o, Irun ori iba jẹ ahọn — ko to o, Olu idariji — dariji wa o, Bi a ba jẹkọ, a darij'ewe, Bi a ba j'ẹran a dari j'eegun o, Ọlọrun wa, Olu idariji —dariji wa o. ASẸ
Hymn xxi – Olu Ọrun awa de | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia