Hymn 884 – IMOLE iyanu ntan | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "IMOLE iyanu ntan" (C&S Hymn #884, Yoruba). 1. IMOLE iyanu ntan Gba Kristien ba nkorin Oluwa ni ngbe ni ro lwosan…
1. IMOLE iyanu ntan Gba Kristien ba nkorin Oluwa ni ngbe ni ro lwosan n'n'apa Re ‘Gba olutunu jin‘na O nfun okan ni‘simi lmole otun y'o la Nigba t'ojo si da. 2. Nigba t‘ero mimo nso L‘ayo la‘wa nlepa lgbala Olorun wa T’a si nri gba l‘otun O ngba wa n‘nu ‘banuje Awa le f‘ayo wipe Je ki ola aimo de Ohun t'o wun k'o je. 3. Ohunkohun t’o le de Jesu y’o gba wa la On t’o wo lili l'aso Y’o fi aso wo wa L'abe orun t‘o teju Ghogbo eda l’o nbo On t‘o nbo eiye orun Y’o bo aw’omo Re. 4. B'ajara tabi opoto Ko lati m'eso wa Bi gbogbo eweko gbe T’ agbo agutan s’egbe Olorun wa mbe sibe Iyin Re y’o kun enu mi Bi mo gbekele E titi Ayo y’o je t’emi. Amin
Hymn 884 – IMOLE iyanu ntan | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia