Hymn 883 – Eyin Oba ogo, On ni Olorun | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "Eyin Oba ogo, On ni Olorun" (C&S Hymn #883, Yoruba). 1. Eyin Oba ogo, On ni Olorun Yin I fun se yanu ti O fi han O wa…
1. Eyin Oba ogo, On ni Olorun Yin I fun se yanu ti O fi han O wa pel’ awon ero mimo l'ona O si je imole won l'osan l‘orun. Egbe: Eyin angel didan lu duru wura Ki gbogbo nyin juba t'e nwo oju Re Ni gbogbo 'joba Re, b'aye ti nyi lo Ise Re y'o ma yin Ise Re y'o ma yin Fi ibukun fun Oluwa okan mi. 2. E yin fun ‘rapada, ti gbogbo okan E yin fun orisun lmularada Fun inu rere ati itoju Re Fun'daniloju pe O ngbo adura. Egbe: Eyin angel didan lu duru... 3. Eyin fun idanwo, bi okun ife T'o aso wa po mo awon ohun orun Fun ‘gbagbo ti nsegun ‘reti ti ki sa Fun ile Ogo t'O ti pese fun wa. Egbe: Eyin angel didan lu duru wura Ki gbogbo nyin juba t'e nwo oju Re Ni gbogbo 'joba Re, b'aye ti nyi lo Ise Re y'o ma yin Ise Re y'o ma yin Fi ibukun fun Oluwa okan mi. Amin
Hymn 883 – Eyin Oba ogo, On ni Olorun | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia