Hymn 885 – L’ORI oke Sion t’o ga j‘orun lo | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "L’ORI oke Sion t’o ga j‘orun lo" (C&S Hymn #885, Yoruba). 1. L’ORI oke Sion t’o ga j‘orun lo N’ilu ‘yanu t’o l‘ewa…
1. L’ORI oke Sion t’o ga j‘orun lo N’ilu ‘yanu t’o l‘ewa pupo Nigboose emi si lo si ilu naa Tori mo n to sura mi sibe. Egbe: Mo n to isura mi si orun I'oke N'ilu t’o dara, ilu ewa Gba t’a ba r’ogo Re, n o ni ere pupo Tori mo n to sura mi sibe. 2. Mo gbo pe le kan n be f’awon eni mimo Ti Olugbala ti lo pese Ita re je wura, at’ opopo wura Emi n to isura mi sibe. Egbe: Mo n to isura mi si... 3. Gbogbo ife okan ati agbara mi At’ise ti mo n se pelu Re Wonyi yoo je oro ti n o ri n’ikehin Tori mo n to sura mi sibe. Egbe: Mo n to isura mi si... 4. Bi mo tile n kiri bi alaini laye N'nu sona at'adura gbogbo Laipe n o gbo ipe ayo lati re le Tori mo n to sura mi Sibe. Egbe: Mo n to isura mi si orun I'oke N'ilu t’o dara, ilu ewa Gba t’a ba r’ogo Re, n o ni ere pupo Tori mo n to sura mi sibe. Amin
Hymn 885 – L’ORI oke Sion t’o ga j‘orun lo | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia