Hymn xviii – Jesu, wa sarin wa | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "Jesu, wa sarin wa" (C&S Hymn #xviii, Yoruba). Jesu, wa sarin wa, L'agbar'Ajinde; Jẹ k'isin wa nihin Jẹ isin ọwọ. Mi…

Hymn xviii – Jesu, wa sarin wa | C&S Yoruba Hymnary
Jesu, wa sarin wa, L'agbar'Ajinde; Jẹ k'isin wa nihin Jẹ isin ọwọ. Mi ẹmi Mimọ Rẹ, Sinu ọkan wa; Mu 'foya at'aro, Kuro l'ọkan wa. Bi a ti n yara lọ, Lọna ajo wa; K'a ma sọna f'ọrọ, T'o j'ayeraye. AMIN

Hymn xviii – Jesu, wa sarin wa | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia