Hymn 872 – EMI Baba Alaye | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "EMI Baba Alaye" (C&S Hymn #872, Yoruba). 1. EMI Baba Alaye Sokale pelu Agbara Pentikosti So okan wa ji Ki O si mu…

Hymn 872 – EMI Baba Alaye | C&S Yoruba Hymnary
1. EMI Baba Alaye Sokale pelu Agbara Pentikosti So okan wa ji Ki O si mu gbona B'ina orun nla Pelu ‘tunu nla Tan ‘mole re. 2. Aye ati emi wa Gba, fi se Tire Ninu isin wa fun O Ka ni ‘ranwo Re Lati j'olotito K’ebun at‘orun Ti Pentikosti Ba s'ori wa. 3. Fi eje ‘yebiye Re T'oke Kalfari We okan ese wa nu Si ra wa pada Fi ‘fe kun aya wa Ka rin ‘na oto lfe Re lao se Bi ti orun. 4. Baba, Omo on Emi Metalokan lae lyin, Ogo, agbara Je Tire nikan Ewa Re l'aye yi Yo je ayo wa Pelu idupe Aleluya! Amin.

Hymn 872 – EMI Baba Alaye | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia