Hymn 873 – AIKU, Airi, Olorun ogbon gbogbo | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "AIKU, Airi, Olorun ogbon gbogbo" (C&S Hymn #873, Yoruba). 1. AIKU, Airi, Olorun ogbon gbogbo O ngbe'nu imole, be l'o…
1. AIKU, Airi, Olorun ogbon gbogbo O ngbe'nu imole, be l'o farasin Olubukun julo, A yin oruko Re. 2. L’aisimi, L'aikanju, O dake roro Nin‘oro, l'aosofo, O njoba ni’pa Ododo Re ga ju awon oke lo Kuuku Re j'orisun ire ati 'fe. 3. O mbukun fun eniyan, t‘omode, t’agba lgbe aye ‘rorun l'o fi fun eda A ngba bi itannna eweko tutu A nwa, ti l’a si nku 'Wo ko yi pada. 4. Oba mi Ologo, Mimo ‘nu imole Awon angel yin O, won bo oju won Awa na y'o yin O, bi awon t'orun Ogo imole l‘o pa O mo fun wa. Amin
Hymn 873 – AIKU, Airi, Olorun ogbon gbogbo | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia