Hymn 871 – OLORUN mi, ‘gba ti mo f'eru ‘yanu | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "OLORUN mi, ‘gba ti mo f'eru ‘yanu" (C&S Hymn #871, Yoruba). 1. OLORUN mi, ‘gba ti mo f'eru ‘yanu Kiyesi ise ti owo re…
1. OLORUN mi, ‘gba ti mo f'eru ‘yanu Kiyesi ise ti owo re se Mo ri ‘rawo, mo gb’ohun aara rti nsan Agbara re tan ka gbogbo aye. Egbe: Okan mi ko ‘rin si Oluwa re Alagbara I’Olorun mi! Okan mi ko ‘rin si Oluwa re Alagbara l'OIorun mi. 2. ‘Gba ti mo rin kaakiri ninu igbo Mo gbo t’awon eye n ko ‘rin didun ‘Gba mo wo ‘le lat’ ori oke giga T’odo n san, t’afefe si fe si mi Egbe: Okan mi ko ‘rin si... 3. ‘Gba ti mo ro o pe ko da Omo re si Lati wa ku, mo roju gba a gbo pe O r'eru ese mi lo lori igi O t’eje Re sile, O ku fun mi. Egbe: Okan mi ko ‘rin si... 4. ‘Gba Kristi yoo de pelu orin ‘segun Wa mu mi lo, ayo yoo gb‘okan mi! 'Gba naa ngo juba, ngo f’irele wole Ngo kede ‘titobi I'Olorun mi!. Egbe: Okan mi ko ‘rin si... Amin
Hymn 871 – OLORUN mi, ‘gba ti mo f'eru ‘yanu | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia