Hymn 868 – KRIST‘ Jesu l'agbara | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "KRIST‘ Jesu l'agbara" (C&S Hymn #868, Yoruba). 1. KRIST‘ Jesu l'agbara Agbara 'dariji Agbara ti n so ni d'aaye T‘o…

Hymn 868 – KRIST‘ Jesu l'agbara | C&S Yoruba Hymnary
1. KRIST‘ Jesu l'agbara Agbara 'dariji Agbara ti n so ni d'aaye T‘o f'iye f'elese Krist’ Jesu l'agbara Rohin re n'bi gbogbo! Gbe okan ebi re to O wa Yoo f’oor’ofe gba O. Egbe: Krist' Jesu l'agbara Agbura Olorun Krist' Jesu I'agbara Mo jo w'okan mi fun Un Krist’ Jesu l'agbara Ngo gbekele E titi Krist' Jesu l’agbara Mo ju ba, wole fun Un. 2. Krist’ Jesu l'agbara Lati so ni d'otun Lati w'ese kuro l'okan Lati so di pipe Krist’ Jesu l’agbara Lati pamo d'opin Ko s’eni‘t'o le ja awon Agutan low Re. Egbe: Krist' Jesu l'agbara... 3. Krist‘ Jesu l‘agbara Lati tu ni ninu Agbara lati ru gbogbo Aniyan okan re Krist’ Jesu l‘agbara Lati n’o’ omije nu Saa f‘igboya ro m’Oluwa Gboran, si gbekele E. Egbe: Krist' Jesu l'agbara... 4. Krist' Jesu l’agbara 'Gbara lati parun Lati bori ota t‘o n fe Gb‘ogun ti okan re Krist' Jesu l'agbara Lor'akete iku Lati f'okan re ni ‘segun Lati ji o dide Egbe: Krist' Jesu l'agbara... Amin

Hymn 868 – KRIST‘ Jesu l'agbara | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia