Hymn 869 – ’BUKUN ni f’awon mimo | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "’BUKUN ni f’awon mimo" (C&S Hymn #869, Yoruba). 1. ’BUKUN ni f’awon mimo Won ti ko ‘se angeli Orun n’ife okan won Won…

Hymn 869 – ’BUKUN ni f’awon mimo | C&S Yoruba Hymnary
1. ’BUKUN ni f’awon mimo Won ti ko ‘se angeli Orun n’ife okan won Won fe lati r’Olorun A we abawon won nu Won n'idapo pelu Re Won dabi Oluwa won Ti ise ere nla fun won. 2. Won n’josin ninu emi Won wole ni’bi'te Re Won te ba nib‘imole lmole Olorun tan Awon olokan-riro Ti won fe lati kekoo Won wa inu Oro naa Titi won fi gb’ohun Re. 3. Oun ni Eleda won Won ba Oun nikan soro Lat‘ooro di asale Ni won nyin l'Ojo ‘sinmi Won di Ii mu ninu laalaa Won gbekele e n'nu ‘ponju lmole Re n tan n'nu won Ayida ko bori re. 4. Oun ni won n yin l'aye won Won ki yoo ri iku mo Won yoo maa b'Oluwa gbe Titi won yoo fi jinde Won yoo sunmo Oluwa Pelu ara ajinde Pelu Baba n'nu Omo At’Emi, metalokan. Amin

Hymn 869 – ’BUKUN ni f’awon mimo | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia