Hymn 867 – GBOGBO‘ogun orun nro keke | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "GBOGBO‘ogun orun nro keke" (C&S Hymn #867, Yoruba). 1. GBOGBO‘ogun orun nro keke Angeli mu harpu won Awon mimo nt‘ohun…

Hymn 867 – GBOGBO‘ogun orun nro keke | C&S Yoruba Hymnary
1. GBOGBO‘ogun orun nro keke Angeli mu harpu won Awon mimo nt‘ohun won se Lati josin t‘o l’ogo Ojo ‘simi t'OIorun de Ojo t'o l'ogo julo Orun kun fun iho ayo A! b’isin won ti dun to. 2. Jek'a pelu awon t‘orun Yin Olorun Oba wa Jek’a pa 'le okan wa mo K'a f‘ohun mimo korin Apere ni ti wa le je T'isimi ti won loke Titi ao fi ri Oluwa Ti a nsin l'ojukoju. 3. K’o to d’igba na, e jeki A ma sin l’ojo keje K’a f‘aniyan wa s'apakan K'a pe sinu ile Re O ti pase k'a ma se be Y'o bukun ipejo wa E jek‘a sin li aisaare Ere re y'o je ti wa. Amin

Hymn 867 – GBOGBO‘ogun orun nro keke | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia