Hymn 846 – JESU mo f'Oruko Re ju gbogbo oko lo | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "JESU mo f'Oruko Re ju gbogbo oko lo" (C&S Hymn #846, Yoruba). JESU mo f'Orukọ Rẹ ju gbogbo okọ lọ, Jesu Oluwa! 'Wọ…
JESU mo f'Orukọ Rẹ ju gbogbo okọ lọ, Jesu Oluwa! 'Wọ l'ohun gbogbo, mi, ko s'ohun to wu mi, Ko s'ohun miran mọ, Jesu Oluwa! 'Wọ Ọmọ Ọlọrun ti fi ẹjẹ, Rẹ ra mi, Jesu Oluwa! A! 'fẹ Rẹ tobi pọ ju gbogbo ifẹ lọ, Ojojumọ l'o n tan, Jesu Oluwa! 'Gba mo sa tọ Ọ, 'Wọ ni yoo s'abo mi, Jesu Oluwa! Aniyan ayé yi ko le dẹru ba mi, Tor' O wa nitosi, Jesu Oluwa! Laipẹ 'Wọ y'o pada, 'gba na n'nu mi yoo dun, Jesu Oluwa! Gbana n o roju Rẹ, 'gba na n ó dabi Rẹ, N ó si wa pẹlu Rẹ, Jesu Oluwa! AMIN
Hymn 846 – JESU mo f'Oruko Re ju gbogbo oko lo | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia