Hymn 826 – SILEKUN fun wa o | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "SILEKUN fun wa o" (C&S Hymn #826, Yoruba). SILẸKUN fun wa o, (2) Iwọ lo ni wa, Mase ta wa nu, Silẹkun fun wa o. Wa…

Hymn 826 – SILEKUN fun wa o | C&S Yoruba Hymnary
SILẸKUN fun wa o, (2) Iwọ lo ni wa, Mase ta wa nu, Silẹkun fun wa o. Wa pese fun wa o (2) Iwọ lo ni wa, Jehofa-Jire, Wa pese fun wa o. Wa f'oyin s'ayé wa, (2) Iwọ l'o l'ayé Jehofa-Nisssi, Wa f'oyin s'ayé wa. Ma jẹ k'a sanwo lọ (2) Bukun fun wa se, Jehofa- Barak, Ma jẹ k'a sanwo lọ. AMIN O! ASẸ. BẸNI K'O RI O

Hymn 826 – SILEKUN fun wa o | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia