Hymn 755 – GB'ohun t'o t'orun wa ti wi | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "GB'ohun t'o t'orun wa ti wi" (C&S Hymn #755, Yoruba). GB'ohun t'o t'ọrun wa ti wi, F'awọn oku mimọ; Didun n'irant'…

Hymn 755 – GB'ohun t'o t'orun wa ti wi | C&S Yoruba Hymnary
GB'ohun t'o t'ọrun wa ti wi, F'awọn oku mimọ; Didun n'irant' orukọ wọn, 'Busun wọn n'itura. Wọn ku n'nu Jesu abukun, Orun wọn ti dun to! Ninu irora oun ẹsẹ, Wọn yọ ninu 'danwo. Lọna jijin s'ayé isẹ, Wọn mbẹ lọd' Oluwa; Isẹ wọn l'ayé iku yi, Pari ni ere nla. AMIN

Hymn 755 – GB'ohun t'o t'orun wa ti wi | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia