Hymn 682 – OJ' ONI lo | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "OJ' ONI lo" (C&S Hymn #682, Yoruba). ỌJ' ONI lọ, Jesu, Baba, Boju Rẹ w'emi ọmọ Rẹ. 'Wọ Imọlẹ, Se 'tọju mi, Tan imọlẹ…

Hymn 682 – OJ' ONI lo | C&S Yoruba Hymnary
ỌJ' ONI lọ, Jesu, Baba, Boju Rẹ w'emi ọmọ Rẹ. 'Wọ Imọlẹ, Se 'tọju mi, Tan imọlẹ Rẹ yi mi ka. Olugbala, N ko ni bẹru, Nitori O wa lọdọ mi. Nigba gbogbo, Ni oju Rẹ, N sọ mi, gba t'ẹnikan ko si. Nigba gbogbo, Ni eti Rẹ, N si si adura ọmọde. Nitori naa, Laisi foya, Mo sun, mo si sinmi le Ọ. Baba, Ọmọ, Ẹmi Mimọ, Ni iyin yẹ l'ọrun, layé. AMIN

Hymn 682 – OJ' ONI lo | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia