Hymn 667 – AWON kekeke wo l'eyi | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "AWON kekeke wo l'eyi" (C&S Hymn #667, Yoruba). AWỌN kekeke wo l'eyi, T' wọn tẹle l'ajo aye ja, Ti wọn si de 'bugbe…

Hymn 667 – AWON kekeke wo l'eyi | C&S Yoruba Hymnary
AWỌN kekeke wo l'eyi, T' wọn tẹle l'ajo aye ja, Ti wọn si de 'bugbe ogo, Eyi ti wọn ti n f'oju si? Ẹmi t'oke Sioni wa Ẹmi lati ilẹ India Ẹmi t'ilẹ Afrika wa Ẹmi lat' erekusu ni. Irin ajo wa ti kọja, Ẹkun ati irora tan; A jumọ pade nikẹhin; Ni ẹnu ibode ọrun. A n reti lati gbọ pe Wa, A sẹgun ẹsẹ oun iku; Gb'ori yin soke, ilẹkun, K'awọn ero ewe wọle. AMIN

Hymn 667 – AWON kekeke wo l'eyi | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia