Hymn 666 – AWON asepe, abura | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "AWON asepe, abura" (C&S Hymn #666, Yoruba). AWỌN asepe, abura At' awọn onija; Ni ijọ kan pẹlu abọ, Ni ki y'o jẹ s'ọwọ…

Hymn 666 – AWON asepe, abura | C&S Yoruba Hymnary
AWỌN asepe, abura At' awọn onija; Ni ijọ kan pẹlu abọ, Ni ki y'o jẹ s'ọwọ wọn. Orin buburu ti wọn n kọ, Jẹ 'rira l'eti mi, K'iru ọrọ buburu wọn , Mase t' ẹnu mi bọ. Awọn alailero ọmọ, Awọn ọmọ-kọmọ- Ki y'o f'ijọ kan j'ẹgbẹ mi, A f'ọlọgbọn ọmọ. Alailojuti ọmọ kan, Ni b'awọn t'o ku jẹ, Elekuru obukọ kan, Ni ko orun w'agbo. Ma jẹ ki n k'ẹgbẹ buburu, Ọlọrun Oluwa; Ki n ma si si ninu wọn, Ti n lọ s'ọrun egbe! AMIN

Hymn 666 – AWON asepe, abura | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia