Hymn 663 – WA ba wa jeun, Oluwa | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "WA ba wa jeun, Oluwa" (C&S Hymn #663, Yoruba). WA ba wa jẹun, Oluwa, Jẹ ka ma yin orukọ Rẹ; Wa busi Ounjẹ wa, si jẹ,…
WA ba wa jẹun, Oluwa, Jẹ ka ma yin orukọ Rẹ; Wa busi Ounjẹ wa, si jẹ, Ka le ba Ọ jẹun l'ọrun. AMIN
Hymn 663 – WA ba wa jeun, Oluwa | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia