Hymn 634 – JI, Okan mi, dide giri | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "JI, Okan mi, dide giri" (C&S Hymn #634, Yoruba). JI, Ọkan mi, dide giri, Ma lepa nso kikan; F'itara sure ije 'yi, Fun…
JI, Ọkan mi, dide giri, Ma lepa nso kikan; F'itara sure ije 'yi, Fun ade ti ki sa. Awọsanma ẹlẹri wa, Ti wọn n f'oju sun Ọ; Gbagbe irin atẹhinwa, Sa ma tẹ siwaju. Ọlọrun n f'ohun igbera Ke si o lat'oke; Tikarẹ l'O n pin ere na, T'o n nọga lati wo. Olugbala 'Wọ l'o n mu mi Bere ije mi yi; Nigba t'a ba de mi l'ade, N ó wolẹ lẹsẹ Rẹ. AMIN
Hymn 634 – JI, Okan mi, dide giri | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia