Hymn 603 – E DIDE Om'ogun igbala | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "E DIDE Om'ogun igbala" (C&S Hymn #603, Yoruba). Ẹ DIDE Ọm'ogun igbala, To rọ mọ Olori wa: Ẹ dide orilẹ-ede, Ki ọta to…

Hymn 603 – E DIDE Om'ogun igbala | C&S Yoruba Hymnary
Ẹ DIDE Ọm'ogun igbala, To rọ mọ Olori wa: Ẹ dide orilẹ-ede, Ki ọta to de Sion, Ẹ kọ orin, to dun pupọ, Ẹ kọ orin to dun pupọ, Bi hiho omi okun, nipa ẹjẹ Olugbala, Awa ju asẹgun lọ, Awa ju asẹgun lọ, Awa ju asẹgun lọ, Nipa ẹjẹ Olugbala, Awa ju asẹgun lọ. Ẹ wa bu omi igbala, Ẹyin ọmọ arayé; Ẹ wa gba igbala lọfẹ, T'Oluwa pese fun wa. Ẹ kọ orin, to dun pupọ, Ẹ kọ orin to dun pupọ, Bi hiho omi okun, nipa ẹjẹ Olugbala, Awa ju asẹgun lọ, Awa ju asẹgun lọ, Awa ju asẹgun lọ, Nipa ẹjẹ Olugbala, Awa ju asẹgun lọ. Jesu f'ogoj' ọdun bẹbẹ, Fun Ẹgbẹ Séráfù yi; Lati fi ra ayé pada, Ninu ẹsẹ wa gbogbo. Ẹ kọ orin, to dun pupọ, Ẹ kọ orin to dun pupọ, Bi hiho omi okun, nipa ẹjẹ Olugbala, Awa ju asẹgun lọ, Awa ju asẹgun lọ, Awa ju asẹgun lọ, Nipa ẹjẹ Olugbala, Awa ju asẹgun lọ. Ogo ni fun Baba, Ọmọ Ẹmi Mimọ lo de yi; Jọwọ fọ gbogbo wa mọ lau, Ninu ẹsẹ wa gbogbo. Ẹ kọ orin, to dun pupọ, Ẹ kọ orin to dun pupọ, Bi hiho omi okun, nipa ẹjẹ Olugbala, Awa ju asẹgun lọ, Awa ju asẹgun lọ, Awa ju asẹgun lọ, Nipa ẹjẹ Olugbala, Awa ju asẹgun lọ. AMIN Ẹ kọ orin, to dun pupọ, Ẹ kọ orin to dun pupọ, Bi hiho omi okun, nipa ẹjẹ Olugbala, Awa ju asẹgun lọ, Awa ju asẹgun lọ, Awa ju asẹgun lọ, Nipa ẹjẹ Olugbala, Awa ju asẹgun lọ.

Hymn 603 – E DIDE Om'ogun igbala | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia