Hymn 604 – EYIN t'oungbe n gbe, e wa mu | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "EYIN t'oungbe n gbe, e wa mu" (C&S Hymn #604, Yoruba). ẸYIN t'oungbẹ n gbẹ, ẹ wa mu, Omi iye ti n san; Lati orisun ti…
ẸYIN t'oungbẹ n gbẹ, ẹ wa mu, Omi iye ti n san; Lati orisun ti Jesu, Lai sanwo l'awa mbu. Wo! b'o ti pẹ to t'ẹ ti n mu Ninu nkan eke, T'ẹ n l'agbara at'ogun yin Ninu nkan t'o n segbe. Jesu wi pé, isura mi, Ko lopin titi lai; Yoo f'ilera lailai fun Awọn t'o gbọ Tirẹ. AMIN
Hymn 604 – EYIN t'oungbe n gbe, e wa mu | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia