Hymn 056 – OLUWA Olorun Oun Aye | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "OLUWA Olorun Oun Aye" (C&S Hymn #056, Yoruba). 1. OLUWA Ọlọrun / Oun Ayé/ Ọlọrun Kérúbù ati Séráfù Mo ti dẹsẹ sọrun…

Hymn 056 – OLUWA Olorun Oun Aye | C&S Yoruba Hymnary
1. OLUWA Ọlọrun / Oun Ayé/ Ọlọrun Kérúbù ati Séráfù Mo ti dẹsẹ sọrun ati ni/ waju Rẹ, Dariji mi. 2. Mo ti f'iwa mi bi Ọ ninu / rekọja! Mo si sako kuro lọdọ Rẹ! layé yi Jọwọ gba mi, ra mi pada lọ / wọ esu, Dariji mi. 3. 'Bode mẹrinlelogun / ọna esu Mase jẹ k'emi kọja / ninu wọn Gba mi lọwọ ẹsẹ aisodo / do gbogbo Dariji mi. 4. Ẹsẹ agbere, ika, oju / kokoro Arankan, ilara, I / paniyan, Gbogbo wọnyi ni mo ti jẹbi ni/ waju Rẹ, Dariji mi. 5. Gbogbo awọn ẹsẹ to le fa / iku wa, Mase jẹ k'emi ninu didun / ninu wọn, Mase jẹ k'esu fi mi / s'ere jẹ, Dariji mi. 6. Ogo ni fun Baba / Ọmọ, Ẹmi Mẹtalọkan Mimọ Alagbara Fa mi yọ kuro ninu ẹsẹ na / tẹwọ gba mi, Dariji mi. AMIN

Hymn 056 – OLUWA Olorun Oun Aye | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia