Hymn 481 – KERUBU Pelu SERAFU | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "KERUBU Pelu SERAFU" (C&S Hymn #481, Yoruba). KÉRÚBÙ pẹlu Séráfù (2) Kọrin Mimọ (2) Ẹ fi iyin fun Baba (2) L'oke Ọrun…
KÉRÚBÙ pẹlu Séráfù (2) Kọrin Mimọ (2) Ẹ fi iyin fun Baba (2) L'oke Ọrun (2) Ọlọrun to gbọ ti Mose (2) L'oke Sinai(2) Jọwọ gbọ temi ọmọ Rẹ (2) Baba Mimọ (2) Ọlọrun to gbọ ti Elijah (2) L'odo Jordan (2) Jọwọ gbọ temi ọmọ Rẹ (2) Baba Mimọ (2) Ọlọrun to gbọ ti Daniel (2) Ninu iho (2) Jọwọ gbọ temi ọmọ Rẹ (2) Baba Mimọ (2) Séráfù pẹlu Kérúbù (2) Damure giri (2) Ọba Olupese (2) Yoo pese fun wa (2) Ẹyin Agba Angẹli (2) Gbadura wa (2) Jah Jehofa (2) Gbọ‘gbe ẹdun wa. (2) AMIN
Hymn 481 – KERUBU Pelu SERAFU | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia