Hymn 447 – BABA, b'ife Re ni, lati | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "BABA, b'ife Re ni, lati" (C&S Hymn #447, Yoruba). BABA, b'ifẹ Rẹ ni, lati Du mi l'ohun ayé, Sa jẹ ki adura mi yii,…
BABA, b'ifẹ Rẹ ni, lati Du mi l'ohun ayé, Sa jẹ ki adura mi yii, Goke de itẹ rẹ. F'ọkan tutu, t'ọpẹ fun mi; . Gba mi lọwọ kikun; Fun mi n'ibukun or'-ọfẹ; Si jẹ ki n wa fun Ọ. K'ero yi pe, 'Wọ ni temi, Ma ba mi lọ layé; Pẹlu mi lọna ajo mi, Si ba mi d'opin rẹ. AMIN
Hymn 447 – BABA, b'ife Re ni, lati | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia