Hymn 400 – OLORUN l'abo eni Re | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "OLORUN l'abo eni Re" (C&S Hymn #400, Yoruba). ỌLỌRUN l'abo ẹni Rẹ, Nigba iji ipọnju de; K'awa to se aroye wa, A! sa wo…

Hymn 400 – OLORUN l'abo eni Re | C&S Yoruba Hymnary
ỌLỌRUN l'abo ẹni Rẹ, Nigba iji ipọnju de; K'awa to se aroye wa, A! sa wo t'oun t'iranwọ Rẹ. B'agbami riru mbu soke, Ọkan wa mbẹ l'alafia; Nigb' orilẹ at' etido, Ba n jaya riru omi na. Iwe ọwọ ni, ọrọ Rẹ; Kawọ ibinu fufu wa; Ọrọ Rẹ m'alafia wa, O f'ilera f'ọkan arẹ. AMIN

Hymn 400 – OLORUN l'abo eni Re | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia