Hymn 364 – F'AWON eniyan Re | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "F'AWON eniyan Re" (C&S Hymn #364, Yoruba). F'AWỌN eniyan Rẹ, T'o ti fi ayé silẹ; Awọn to mo Ọ, t'o sin Ọ, Gba orin…

Hymn 364 – F'AWON eniyan Re | C&S Yoruba Hymnary
F'AWỌN eniyan Rẹ, T'o ti fi ayé silẹ; Awọn to mo Ọ, t'o sin Ọ, Gba orin iyin wa. F'awọn eniyan Rẹ, Gba ohun ọpẹ wa; Awọn t'o fi Ọ s'ẹsan wọn, Wọn ku n'igbagbọ Rẹ! Ni gbogbo ayé wọn, 'Wọ ni wọn n wo l'oju; Ẹmi Mimọ Rẹ l'o n kọ wọn, Lati s'ohun gbogbo. Fun eyi, Oluwa, cr A n yin orukọ Rẹ; Jẹ k'a ma tẹle iwa wọn, di Ki a le ku bi wọn. AMIN

Hymn 364 – F'AWON eniyan Re | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia