Hymn 360 – A WA f'ori bale fun/ O Jesu | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "A WA f'ori bale fun/ O Jesu" (C&S Hymn #360, Yoruba). A WA f'ori balẹ fun/ Ọ Jesu, 'Wọ ti s'Olori Ijọ awọn / eniyan…

Hymn 360 – A WA f'ori bale fun/ O Jesu | C&S Yoruba Hymnary
A WA f'ori balẹ fun/ Ọ Jesu, 'Wọ ti s'Olori Ijọ awọn / eniyan Rẹ, Ijọ ti mbẹ layé yi, a / ti lọ / run pẹlu; Alleluya! 'Wọ t'o ku to si jin / de fun wa, T'o mbẹ lọdọ Baba bi Ala / gbawi wa K'ogo at'ọla nla / jẹ Tirẹ Alleluya! Ati ni ọjọ nla Pẹn / tikọsti, Ti o ran Parakliti / si ayé, Olutunu nla Rẹ ti / mbẹ wa gbe; Alleluya! Lat' ori itẹ Rẹ lo / ke ọrun, L'O si ń wo gbogbo awọn o / jisẹ Rẹ, T' o si ń sikẹ gbogbo awọn Ajẹ / riku Rẹ. Alleluya! A fi iyin at'ọla nla f'o / orukọ Rẹ, p N'tori iku gbogbo awọn o / jisẹ Rẹ, Ni gbogbo ilẹ A/gbaye yi Alleluya! AMIN

Hymn 360 – A WA f'ori bale fun/ O Jesu | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia