Hymn 267 – Ise gbogbo ti awa n se | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "Ise gbogbo ti awa n se" (C&S Hymn #267, Yoruba). 1. Isẹ gbogbo ti awa n se, Ni Ọlọrun ti ri; Ero gbogbo t'o wa ninu,…
1. Isẹ gbogbo ti awa n se, Ni Ọlọrun ti ri; Ero gbogbo t'o wa ninu, Ni Ọlọrun si mọ. 2. A ko le f'ẹsẹ wa pamọ, Gbogbo wọn l'O ti mọ; A n purọ, a n tan 'ra wa jẹ, B'a ro pe ko mọ wọn. 3. Ohun gbogbo han ni gbangban, Ni oju Ọlọrun; Okunkun ati imọlẹ, Si ri bakan naa fun. 4. Ọlọrun, jẹ k'a ranti pe, Oju rẹ si ri wa; Si jẹ ki awa k'o bẹru, Lati dẹsẹ si Ọ. AMIN
Hymn 267 – Ise gbogbo ti awa n se | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia