Hymn 233 – ESE won ti da to | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "ESE won ti da to" (C&S Hymn #233, Yoruba). 1. ẸSẸ wọn ti da to! Ti n duro ni Sion; Awọn t'o mu 'hin gbala wa, Awọn t'o…

Hymn 233 – ESE won ti da to | C&S Yoruba Hymnary
1. ẸSẸ wọn ti da to! Ti n duro ni Sion; Awọn t'o mu 'hin gbala wa, Awọn t'o f'ayọ han 2. Ohun wọn ti wọ to! Ihin naa ti dun to! Sion, w'Ọlọrun Ọba rẹ B'o ti sẹgun nihin. 3. Eti wa ti yọ to! Lati gbọrọ ayọ; Woli, Ọba, ti duro de, Wọn wa, wọn ko si ri. 4. Oju wa ti yọ to! T'o ri 'mọlẹ ọrun; Ọba, Woli, wọn wa titi, Wọn si ku, wọn ko ri. 5. Oluwa, f'ipa han; Lori gbogbo ayé; Ki gbogbo orilẹ ede, W'Ọba Ọlọrun won. AMIN

Hymn 233 – ESE won ti da to | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia