Hymn 197 – OJO nla kan ma mbo | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "OJO nla kan ma mbo" (C&S Hymn #197, Yoruba). 1. ỌJỌ nla kan ma mbọ, T' Olusiro y'o de, Gbogbo eniyan yoo ri, Ayé yoo…

Hymn 197 – OJO nla kan ma mbo | C&S Yoruba Hymnary
1. ỌJỌ nla kan ma mbọ, T' Olusiro y'o de, Gbogbo eniyan yoo ri, Ayé yoo wariri. 2. Igbagbọ rẹ ha da? 'Wọ ti ko m'Ọlọrun, T'o f'ẹda se igbẹkẹle, T'o f'Oluwa silẹ. 3. Ayọ pupọ yoo wa, L'ọkan ti Jesu ń gbe, Ti wọn ti kọ ayé silẹ, T'o gba Ẹmi Mimọ. 4. Ẹ ku 'sẹ Oluwa, Ẹyin ara at'ọrẹ, Ki Baba Olodumare, Bukun fun gbogbo wa. AMIN

Hymn 197 – OJO nla kan ma mbo | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia