Hymn 18 – WA s'adura ooro | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "WA s'adura ooro" (C&S Hymn #18, Yoruba). 1. WA s'adura oorọ, Kunlẹ k'a gbadura; f Adura ni ọpa Kristiani, Lati…
1. WA s'adura oorọ, Kunlẹ k'a gbadura; f Adura ni ọpa Kristiani, Lati b'Ọlọrun rin. 2. Lọsan, wolẹ labẹ, Apat' ayeraye; f Itura ojiji Rẹ dun, Nigba t'orun ba mu. 3. Jẹ ki gbogbo ile, Wa gbadura l'alẹ; Ki ile wa di t'Ọlọrun, di Ati 'bode ọrun. 4. Nigba ti o d'ọganjọ, Jẹ k'a wi l'ẹmi, pe, Mo sun, sugbọn ọkan mi ji Lati ba Ọ sọna. AMIN
Hymn 18 – WA s'adura ooro | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia