Hymn 163 – Adaba Mimo sokale | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "Adaba Mimo sokale" (C&S Hymn #163, Yoruba). 1. Adaba Mimọ sọkalẹ, Ko wa fun wa ni agbara Adaba Mimọ sọkalẹ. 2. Adaba…

Hymn 163 – Adaba Mimo sokale | C&S Yoruba Hymnary
1. Adaba Mimọ sọkalẹ, Ko wa fun wa ni agbara Adaba Mimọ sọkalẹ. 2. Adaba Mimọ sọkalẹ, Ko wa fun wa ni isẹgun, Adaba Mimọ sọkalẹ. 3. Adaba Mimọ sọkalẹ, Ko wa fun wa ni ibukun, Adaba Mimọ sọkalẹ. 4. Adaba Mimọ sọkalẹ, Sure fun wa l'ọjọ oni, Adaba Mimọ sọkalẹ. AMIN

Hymn 163 – Adaba Mimo sokale | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia