Hymn 142 – GBOGBO Egbe Akorin | C&S Yoruba Hymnary

Read, copy, and download the lyrics of "GBOGBO Egbe Akorin" (C&S Hymn #142, Yoruba). 1. GBOGBO Ẹgbẹ Akọrin ) A ki yin ku 'yedun ) 2ce Ọlọrun k'o ran yin lọwọ,…

Hymn 142 – GBOGBO Egbe Akorin | C&S Yoruba Hymnary
1. GBOGBO Ẹgbẹ Akọrin ) A ki yin ku 'yedun ) 2ce Ọlọrun k'o ran yin lọwọ, Lati sisẹ d'opin. A! Ọpẹ yẹ Ọ, Baba Olodumare, A! Ọpẹ yẹ Ọ, Olodumare. 2. Gbogbo Ẹgbẹ Marta, ) A ki yin ku 'yedun; ) 2ce K'Ọlọrun k'o ran yin lọwọ Ka le se l'aseye. 3. Gbogbo Ọdọmọkunrin, ) A ki yin ku 'yedun )2ce K'Ọlọrun ko ran yin lọwọ Lati sisẹ d'opin 4. Gbogbo ẹyin Ẹsita ) A ki yin ku 'yedun ) 2ce K'Ọlọrun ko ran yin lọwọ Lati sisẹ d'opin 5. Gbogbo ẹyin Ẹgbẹ Mary, ) A ki yin ku 'yedun )2ce K'Ọlọrun ko ran yin lọwọ Lati sisẹ d'opin 6. Gbogbo Ẹgbẹ Aladura ) A ki yin ku 'yedun ) 2ce K'Ọlọrun ko ran yin lọwọ Lati sisẹ d'opin 7. A f'ogo fun Baba wa ) A f'ogo fun Ọmọ, ) 2ce A f'ogo fun Ẹmi Mimọ , Mẹtalọkan lailai. AMIN

Hymn 142 – GBOGBO Egbe Akorin | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia