Hymn 937 – lSEGUN wa li okan mi | C&S Yoruba Hymnary
Read, copy, and download the lyrics of "lSEGUN wa li okan mi" (C&S Hymn #937, Yoruba). 1. lSEGUN wa li okan mi Nitori Emi ngbe 'nu mi Jeki igbi idanwo de Jesu…
1. lSEGUN wa li okan mi Nitori Emi ngbe 'nu mi Jeki igbi idanwo de Jesu mura lati gba mi. Egbe: Isegun! Isegun! isegun l‘okan mi Mo ni isegun nla ‘tori Jesu gb‘okan mi Isegun! lsegun! bi odo sisan Mo nsegun nla ninu eje Jesu. 2. Bi ‘ja tile le to si pe Bi esu tile b‘okan mi ja Sibe, mo je alagbara L’agbara Jesu, ngo segun. Egbe: Isegun! Isegun!... 3. Mo ni ‘segun lori ese Mo ni segun lori ‘boji Ani iku ko ni ‘pa mo Aleluya! emi ti la. Egbe: Isegun! Isegun! isegun l‘okan mi Mo ni isegun nla ‘tori Jesu gb‘okan mi Isegun! lsegun! bi odo sisan Mo nsegun nla ninu eje Jesu. Amin
Hymn 937 – lSEGUN wa li okan mi | C&S Yoruba Hymnary on Seraphmedia